“Ofo Para Vitalidade”
Eye finfin apa mi otun,
Igba
obi ifin ni i je,
Eye finfin apa mi osi,
Igba
obi ipa ni i je,
Eyi mafun mafun ringindin to ti inu oga fo
waye,
Igba
atare ni je,
Oun ni Orunmila
da nigba ti o nsojojo,
Ti awon
ota re ni ko ni dide,
Ifa ni
ti o ba se ti Alajogun ni,
Pere ni
tewe iyeye,
Alooye
ni ti peregun,
Piri ni
eye olongo ji,
A ki ba olokunrun eye lori ite,
Gege lowu alantakun i fuyee,
Oota ki ku,
Oota ki run,
Kooko
lara ota le.
Nenhum comentário:
Postar um comentário